Sola Allyson – Ebe Lyrics + Mp3 Download

2617
Sola Allyson – Ebe Lyrics + Mp3 Download

Sola Allyson – Ebe

The song “Ebe”, which means plead in English serves as the seventh track from Sola Allyson‘s 2018 album, Imuse.

Ebe! is a song of submission and supplication to The Almighty.



LYRICS

Lord, I’ve come to seek your face
Let Your grace and Your mercy
Come upon me Lord

Oh Lord, I call upon Your name
Let the rain of Your mercy
Pour upon me, Lord

Oluwa, mo wa si bi ite
Je ki ore ofe ati aanu re, Oluwa
Ko ba le mi l’ori

Oluwa, mo ke pe oruko re
Je ki ojo aanu re o, Baba
Ko ro s’ori iseda mi

Chorus

Baba, ooo
Eyi l’ebe o /4x

Baba alaanu
Olugbe’be, gbo ebe mi oluwa
Aye mi ko bu ola fun o ni mo n bere
Ona mi toro ko di tito ninu ife re oluwa ooo
Eyi l’ebe mi oo


Gbami l’owo asise, oluwa
Gbami l’owo ogun t’apa obi mi o ka
Gbami l’owo ogun irandiran
Gbami o Baba
Iwo ni mo gbe ke le, eni to l’emi mi
Oluwa to wo batilomeu afoju san
Oba to ji oku omo jiari dide
Oku lasaru ojo merin oti nra, oti nrun


Iwo lo jii dide ooo
Oluwa s’aanu mi
Jesu omo dafidi gbo adu’a mi
Ore ofe re ni mo bere
Aye o seegbe lai si ore ofe re, oluwa ooo
Mo fi ore ofe re r’ayegbe, oluwa
Atupa imo mi ko ma se ku lai lai
Iwo ni opo fitila to ntan si emi mi, oluwa
Oro re wipe bi mo bere maa ri gba
Mo n bere ki n ri gba


Bi mo baa ka l’ekun, ilekun aasi
Ilekun ko si
Asi ti ko wipe
Bi mo ba wa kiri, maa ri
Mo n wa kiri, ki n ri o
Ki ni ere to po
Ohun gbogbo to wa ninu iseda
N gbimo aanu si ayanmo mi
Won sise iranwo lori ayanmo mi, oluwa oo
Ileku si ‘le
Ileku aanu si ‘le, oluwa
Aanu ro s’ori mi, o ro s’ori mi be
Olugb’ebe, gbo ebe mi oo

Outro

Lord, I’ve come to seek your face
Let Your grace and Your mercy
Come upon me Lord

Oh Lord, I call upon Your name
Let the rain of Your mercy
Pour upon me, Lord

Oluwa, mo wa si bi ite
Je ki ore ofe ati aanu re, Oluwa
Ko ba le mi l’ori

Oluwa, mo ke pe oruko re
Je ki ojo aanu re o, Baba
Ko ro s’ori iseda mi

Chorus

Baba, ooo
Eyi l’ebe o /2x

OpraDre

Subscribe
Notify of
guest
0 Comments
oldest
newest most voted
Inline Feedbacks
View all comments