EmmaOMG – Oba Ni Jesu Mp3 + Lyrics Download

22823
EmmaOMG - Oba Ni Jesu Mp3+ Lyrics Download

EmmaOMG – Oba Ni Jesu Mp3 + Lyrics Download

Prolific Nigerian Christian/Gospel Artiste EmmaOMG releases a new single which he titles “Oba Ni Jesu” alongside The OhEmGee Band. This song is sure to bless your heart and uplift your spirit.

Lyrics: Oba Ni Jesu by EmmaOMG

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oh! Oh! Oba ni Jesu

Mo ti sonu sinu igbekun ese mi
Si afonifoji iku a ti gbagbe mi
A ti to mi pin pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo jebi gbogbo esun ta kan mo mi

Ide mi ja, mo d’ominira
Lati igba mo ti mo Jesu
A ti san gbese mi nipa Eje Jesu

Jesus, yours is the victory
Hallelujah! Praise the one who sets me free
Hallelujah! Death has lost his grip on me
You have broken every chain
There is salvation in your name
Jesus Christ, my living hope

#OpraDre

Subscribe
Notify of
guest
1 Comment
oldest
newest most voted
Inline Feedbacks
View all comments
aizha
1 year ago

Wow I Love This Song